Nigbakuugba ti a ba menuba awon iserun eni awon eni igbaani to se awon eniyan kan sile ni a n tokasi. Bi a ba si menubaawon iserun, awon to ti ku ni a n tokasi pelu kii se alaaye. Bi baba ati iya to bi ni ba ku, iserun eni ni awon mejeeji, bi o ba si je pe baba ati iya to bi awon obi wa naa ba si ti ku iserun eni ni awon naa. Bee ni a le maa tan an titi de ori eni to te agbo ile tabi eni to se idile tabi iran kan sile. Iserun eni ni eni to se orile iran eni sile nigba laelae.
Oju orori loori se pataki ni ile Yoruba. Oju oori ni ibi ti a sin oku si. Igbagbo Yoruba ni pe gbogbo igba ti a ba pe oku ni oju oori re, yoo dahun yoo si se ohun ti a ba fe.
Idi ti a fi gbagbo ninu awon iserun eni:
Ona ti a n gba tu won loju
Click here to ask a question and get an answer published in the forum. Read our disclaimer.
Get paid for every topic you create in: Shoutam.com Forum!