Konsonanti aferigipe asenupe

All QuestionsCategory: Secondary SchoolKonsonanti aferigipe asenupe
Tina asked 4 years ago

Click here to ask a question and get an answer published in the forum. Read our disclaimer.

Get paid for every topic you create in: Shoutam.com Forum!MAKE-MONEY

3 Answers
User AvatarStopLearn Team Staff answered 4 years ago

Awon koko to se pataki fun sise alaye iro konsonanti niwonyi:
1. Ohun to n sele si tan-an-na
2. Ipo ti afase wa ( riranmu ati airanmu)
3. Ibi isenu pe iro konsonanti
4. Ona isenupe iro konsonanti

1. Ohun to n sele si tan-an-na :- 
Bi a ba pe iro konsonanti ede Yoruba, isesi tan-an-na le mu ki o wa nipo akunyun tabi aikunyun. Awon iro konsonanti aikunyun ni ( t, k, p, f, s, s ) nitori eemi to n bo lati edo-foro n raye gba tan-an-na koja laisi idiwo. Awon iro konsonanti akunyun ni (b, d, g, gb, j, l, m, w, y ) nitori eemi to n gba inu tan-an-na ko raye koja woorowo.

2. Ipo ti afase wa (rirammu ati airanmu): 
Iro konsonanti airanmupe ni (b, d, f, g, gb, h, j, k, l, p, r, s, s, t, w, y) nitoripe afase gba soke ti eemi si n gba inu enu nikan jade nigba ti a n pe awon iro wonyi. Awon iro konsonanti aranmupe ni (m, n) nitori pe afase ko gba soke ti eyi si je ki eemi ti n bo lati inu edo-foro maa gba enu ati iho-imu nigba ti a n pe awon iro yii.

3. Ibi isenupe iro konsonanti: 
(a) Afetepe = b, m, 
(b) Afeyinfetepe = f 
(d) Aferigipe = t, d, s, l, m, f 
(e) Afajape = y 
(e) Afajaferigipe = s, j 
(f) Afafasepe = k, g 
(g) Afitan-an-nape = h 
(gb) Afafasefetepe = p, gb, w.

  1. Ona isenupe iro konsonanti:
    Eyi maa n salaye ipo afase, iru eemi ti a lo, iwasi eya-ara fun iro pipe
    (a) Asenupe = b, t, d, k, p, gb. (Afipe asunsi ati akanmole yoo pade, afase yoo sigbe soke).
    (b) Afunupe = f, s, s, h. (Eya ara fun iro pipe yoo sumo ara won ti aaye kekere yoo wa fun eemi).
    (d) Aseesetan = y, w. (Enu nikan ni eemi maa n gba jade ti a ba pe awon iro wonyi).
    (e) Aranmupe = m, n. (Eemi yoo ma gba iho-imu koja).
    (e) Asesi = j. (Awon afipe re kii tete pinya, a oo si gbo ariwo ti o han daadaa nigba ti a ba pe e).
    (f) Afegbe-enu-pe = i. (Eemi maa n gba egbe enu kan koja nigba ti egbe enu keji ti di pa).
    (g) Arehon = r. (Ahon maa n re mo erigi oke nigba ti a ba pe iro yii).

Thanks for the source

Click here to ask a question and get an answer published in the forum. Read our disclaimer.

Get paid for every topic you create in: Shoutam.com Forum!MAKE-MONEY

Oluwaseun Badmus answered 3 years ago

Thanks so much for this stoplearn. Please, can I get the consonant chat in Yoruba i.e the place/manner of articulation, place of glottis, etc. will be in Yoruba?

Your Answer

17 + 3 =